Baba Dayo ni ǹkan tí òun ti rí nípa ọmọ rẹ̀ tó ni Downsyndrome fi han pé kò sí ọmọ ti ko wúlò . Usman Yahaya to jẹ́ bàbá Dayo ni bí àwọn ṣe bi Dayo ni iya oun ti gbà ọmọ náà láti tójú, ṣùgbọ́n àsìkò ...